Kayeefi!
Baba pa omo
re lasiko to n ba iyawo re ja
Ade Oniroyin
Owo ileese olopaa ipinle Eko ti te okunrin
kan, Ayobami
Isiaka lori esun po pa omo re, omo odun kan laduugbo Ijaye nitosi Iseri niluu
Eko.
Gege bi alukoro ileese olopaa ipinle Eko, Bala Elkana se so
ninu atejade kan to fi sita lojo sannde ana, Ayobami pa omo re ohun t’oruko re
n je Nana lasiko tie de aiyede kan waye laarin oun atiyawo re. akoroyin wa gbo
pe, nise ni okunrin yii sadeede gba omo lowo iyawo re, to si la ori re mole.
O soo di mimo pe, nise loei Nana fo yanga yanga loju ese
nibe pelu afikun pe omooya Ayobami lo mu esun ohun lo si ago olopaa. Ninu oro
re, Elkana ni “lojo sannde, ojo kerindinlogbon osu yii ni deedee aago meje ku
iseju mewaa, okunrin kan, Alaaji Garuba
Isiaka mu esun lo si ago olopaa pe lojo naa, lasiko toun wa ni Berger, ni aburo
oun kan, Alaaji Mohammad Isiaka foonu pe, Ayobami Isiaka ti fi tipatipa gba omo
re obinrin omo odun kan, Nana lowo iya re, to si lee mole”
“Ori omo naa fo tutu, to si ku loju ese nibe. Ti ko ba si si
tawon olopaa to tete de ibi isele ohun, nise lawon eeyan to wa nitosi ki ba luu
pa. Laipe ni yoo si foju ba ile-ejo.”
No comments:
Post a Comment